Diutarónómì 32:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Wọ́n ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run+ mú mi bínú;*Wọ́n ti fi àwọn òrìṣà+ wọn tí kò ní láárí múnú bí mi. Torí náà, màá fi àwọn tí kì í ṣe èèyàn+ mú kí wọ́n jowú;Màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀+ mú wọn bínú. Nehemáyà 9:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “Àmọ́, wọ́n ya aláìgbọràn, wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí ọ,+ wọ́n sì kẹ̀yìn sí Òfin rẹ.* Wọ́n pa àwọn wòlíì rẹ tó kìlọ̀ fún wọn láti mú wọn pa dà sọ́dọ̀ rẹ, wọ́n sì hu ìwà àìlọ́wọ̀ tó bùáyà.+
21 Wọ́n ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run+ mú mi bínú;*Wọ́n ti fi àwọn òrìṣà+ wọn tí kò ní láárí múnú bí mi. Torí náà, màá fi àwọn tí kì í ṣe èèyàn+ mú kí wọ́n jowú;Màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀+ mú wọn bínú.
26 “Àmọ́, wọ́n ya aláìgbọràn, wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí ọ,+ wọ́n sì kẹ̀yìn sí Òfin rẹ.* Wọ́n pa àwọn wòlíì rẹ tó kìlọ̀ fún wọn láti mú wọn pa dà sọ́dọ̀ rẹ, wọ́n sì hu ìwà àìlọ́wọ̀ tó bùáyà.+