Àìsáyà 24:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà ti ba ibẹ̀ jẹ́,+Torí wọ́n ti rú òfin,+Wọ́n ti yí ìlànà pa dà,+Wọ́n sì da májẹ̀mú tó wà pẹ́ títí.*+ Jeremáyà 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Lẹ́yìn náà, mo mú yín wá sí ilẹ̀ eléso,Kí ẹ lè máa jẹ èso rẹ̀ àti àwọn ohun rere rẹ̀.+ Ṣùgbọ́n ẹ wọlé wá, ẹ sì sọ ilẹ̀ mi di ẹlẹ́gbin;Ẹ sọ ogún mi di ohun ìríra.+
5 Àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà ti ba ibẹ̀ jẹ́,+Torí wọ́n ti rú òfin,+Wọ́n ti yí ìlànà pa dà,+Wọ́n sì da májẹ̀mú tó wà pẹ́ títí.*+
7 Lẹ́yìn náà, mo mú yín wá sí ilẹ̀ eléso,Kí ẹ lè máa jẹ èso rẹ̀ àti àwọn ohun rere rẹ̀.+ Ṣùgbọ́n ẹ wọlé wá, ẹ sì sọ ilẹ̀ mi di ẹlẹ́gbin;Ẹ sọ ogún mi di ohun ìríra.+