ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 25:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Olórí ẹ̀ṣọ́ tún mú Seráyà+ olórí àlùfáà àti Sefanáyà+ àlùfáà kejì pẹ̀lú àwọn aṣọ́nà mẹ́ta.+

  • 2 Àwọn Ọba 25:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ọba Bábílónì ṣá wọn balẹ̀, ó sì pa wọ́n ní Ríbúlà ní ilẹ̀ Hámátì.+ Bí Júdà ṣe lọ sí ìgbèkùn láti ilẹ̀ rẹ̀ nìyẹn.+

  • Jeremáyà 21:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Jeremáyà gbọ́ ọ̀rọ̀ látọ̀dọ̀ Jèhófà, nígbà tí Ọba Sedekáyà+ rán Páṣúrì+ ọmọ Málíkíjà àti Sefanáyà+ ọmọ Maaseáyà, àlùfáà sí i, pé: 2 “Jọ̀wọ́ bá wa wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà, torí pé Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ń bá wa jà.+ Bóyá Jèhófà á ṣe ọ̀kan lára àwọn iṣẹ́ àrà rẹ̀ nítorí wa, kí ọba yìí lè pa dà lẹ́yìn wa.”+

  • Jeremáyà 37:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ọba Sedekáyà rán Jéhúkálì  + ọmọ Ṣelemáyà àti Sefanáyà+ ọmọ àlùfáà Maaseáyà sí wòlíì Jeremáyà pé: “Jọ̀wọ́, bá wa gbàdúrà sí Jèhófà Ọlọ́run wa.”

  • Jeremáyà 52:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Olórí ẹ̀ṣọ́ tún mú Seráyà+ olórí àlùfáà àti Sefanáyà+ àlùfáà kejì pẹ̀lú àwọn aṣọ́nà mẹ́ta.+

  • Jeremáyà 52:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Ọba Bábílónì ṣá wọn balẹ̀, ó sì pa wọ́n ní Ríbúlà+ ní ilẹ̀ Hámátì. Bí Júdà ṣe lọ sí ìgbèkùn láti ilẹ̀ rẹ̀ nìyẹn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́