Diutarónómì 10:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí Jèhófà Ọlọ́run yín jẹ́ Ọlọ́run àwọn ọlọ́run+ àti Olúwa àwọn olúwa, Ọlọ́run tó tóbi, tó lágbára, tó sì yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù, tí kì í ṣe ojúsàájú sí ẹnikẹ́ni,+ tí kì í sì í gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀. Sáàmù 136:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 136 Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, nítorí ó jẹ́ ẹni rere;+Ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.+ 2 Ẹ fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run àwọn ọlọ́run,+Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.
17 Torí Jèhófà Ọlọ́run yín jẹ́ Ọlọ́run àwọn ọlọ́run+ àti Olúwa àwọn olúwa, Ọlọ́run tó tóbi, tó lágbára, tó sì yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù, tí kì í ṣe ojúsàájú sí ẹnikẹ́ni,+ tí kì í sì í gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀.
136 Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, nítorí ó jẹ́ ẹni rere;+Ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.+ 2 Ẹ fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run àwọn ọlọ́run,+Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.