Sunday
“. . . nígbà náà ni òpin yóò dé”—Mátíù 24:14
Àárọ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 84 àti Àdúrà 
- 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Fara Wé Àwọn Tó Gba Ìhìn Rere Gbọ́ - • Sekaráyà (Hébérù 12:5, 6) 
- • Èlísábẹ́tì (1 Tẹsalóníkà 5:11) 
- • Màríà (Sáàmù 77:12) 
- • Jósẹ́fù (Òwe 1:5) 
- • Síméónì àti Ánà (1 Kíróníkà 16:34) 
- • Jésù (Jòhánù 8:31, 32) 
 
- 11:05 Orin 65 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Ìdí tí Ìròyìn Burúkú Ò Fi Bà Wá Lẹ́rù (Sáàmù 112:1-10) 
- 11:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 12:15 Orin 61 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀sán
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 122 
- 1:50 BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI Ń SỌ ÌTÀN: “A Ò Ní Fi Falẹ̀ Mọ́” (Ìfihàn 10:6) 
- 2:20 Orin 126 àti Ìfilọ̀ 
- 2:30 Kí Lo Rí Kọ́? 
- 2:40 ‘Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká ‘Di Ìhìn Rere Mú Ṣinṣin,’ Báwo La Ṣe Lè Ṣe Bẹ́ẹ̀? (1 Kọ́ríńtì 2:16; 15:1, 2, 58; Máàkù 6:30-34) 
- 3:30 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí