Saturday
“Ẹ máa kéde ìhìn rere ìgbàlà rẹ̀ láti ọjọ́ dé ọjọ́”—Sáàmù 96:2
Àárọ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 53 àti Àdúrà 
- 9:40 “Mo Gbọ́dọ̀ . . . Kéde Ìhìn Rere Ìjọba Ọlọ́run” (Lúùkù 4:43) 
- 9:50 FÍDÍÒ ÌTÀN BÍBÉLÌ: - Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 1 - Ìmọ́lẹ̀ Tòótọ́ fún Aráyé—Apá Kejì (Mátíù 2:1-23; Lúùkù 2:1-38, 41-52; Jòhánù 1:9) 
- 10:25 Orin 69 àti Ìfilọ̀ 
- 10:35 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Ṣẹ! - • Ìránṣẹ́ kan wá ṣáájú rẹ̀ (Málákì 3:1; 4:5; Mátíù 11:10-14) 
- • Wúńdíá ló bí i (Àìsáyà 7:14; Mátíù 1:18, 22, 23) 
- • Wọ́n bí i sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù (Míkà 5:2; Lúùkù 2:4-7) 
- • Ohunkóhun ò ṣe é ní kékeré (Hósíà 11:1; Mátíù 2:13-15) 
- • Wọ́n pè é ní ará Násárẹ́tì (Àìsáyà 11:1, 2; Mátíù 2:23) 
- • Ó dé ní Àkókò tí Bíbélì sọ (Dáníẹ́lì 9:25; Lúùkù 3:1, 2, 21, 22) 
 
- 11:40 ÌRÌBỌMI: Máa “Ṣègbọràn sí Ìhìn Rere” (2 Kọ́ríńtì 9:13; 1 Tímótì 4:12-16; Hébérù 13:17) 
- 12:10 Orin 24 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀sán
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 83 
- 1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Fi Ìròyìn Rere Paná Ìròyìn Burúkú - • Òfófó (Àìsáyà 52:7) 
- • Ẹ̀rí Ọkàn Tó Ń Dani Láàmú (1 Jòhánù 1:7, 9) 
- • Àwọn Nǹkan Tó Ń Ṣẹlẹ̀ Láyé (Mátíù 24:14) 
- • Ìrẹ̀wẹ̀sì (Mátíù 11:28-30) 
 
- 2:35 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: “Ara Mi Wà Lọ́nà Láti Kéde Ìhìn Rere” - • Kì í Ṣe Iṣẹ́ Àwọn Àpọ́sítẹ́lì Nìkan (Róòmù 1:15; 1 Tẹsalóníkà 1:8) 
- • Ara Ìjọsìn Wa Ni (Róòmù 1:9) 
- • Rí I Pé O Ní Àwọn Nǹkan Tó Yẹ (Éfésù 6:15) 
 
- 3:15 FÍDÍÒ: “Bí Ìhìn Rere Náà Ṣe Ń So Èso, Tó sì Ń Gbilẹ̀ ní Gbogbo Ayé” (Kólósè 1:6) 
- 3:40 Orin 35 àti Ìfilọ̀ 
- 3:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Wàásù Ìhìn Rere - • Níbikíbi Tó O Bá Wà (2 Tímótì 4:5) 
- • Níbikíbi Tí Ẹ̀mí Ọlọ́run Bá Darí Ẹ Sí (Ìṣe 16:6-10) 
 
- 4:15 Kí Lo Máa Ṣe “Nítorí Ìhìn Rere”? (1 Kọ́ríńtì 9:23; Àìsáyà 6:8) 
- 4:50 Orin 21 àti Àdúrà Ìparí