Má Ṣojo!
ÒWÚRỌ̀
- 9:30 Ohùn Orin 
- 9:40 Orin 73 àti Àdúrà 
- 9:50 Jèhófà Ni Kì Í Jẹ́ Ká Ṣojo 
- 10:05 Àpínsọ Àsọyé: Jẹ́ Aláìṣojo Bíi Ti . . . - Énọ́kù 
- Mósè 
- Jèhóṣáfátì 
- Pétérù 
 
- 11:05 Orin 69 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 Ẹ Mọ́kàn Le Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù 
- 11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:00 Orin 48 
Ọ̀SÁN
- 1:10 Ohùn Orin 
- 1:20 Orin 63 àti Àdúrà 
- 1:30 Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn: Pinnu Pé Ìsìn Tòótọ́ Lo Máa Ṣe 
- 2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:30 Orin 76 àti Ìfilọ̀ 
- 2:40 Àpínsọ Àsọyé: Jẹ́ Aláìṣojo Bíi Ti Kristi Táwọn Èèyàn Bá Ń Fúngun Mọ́ Ẹ - Nínú Ìdílé 
- Nílé Ìwé 
- Níbi Iṣẹ́ 
- Ní Àdúgbò 
 
- 3:40 Jèhófà Máa San Ẹ́ Lẹ́san “Ńláǹlà” Tó Ò Bá Ṣojo 
- 4:15 Orin 119 àti Àdúrà