“ÌFẸ́ Ń GBÉNI RÓ”
ÒWÚRỌ̀
- 9:30 Ohùn Orin 
- 9:40 Orin 90 àti Àdúrà 
- 9:50 “Ìmọ̀ Máa Ń Gbéra Ga, Àmọ́ Ìfẹ́ Ń Gbéni Ró” 
- 10:05 Àpínsọ Àsọyé: Wọ́n Gbé Àwọn Míì Ró - Bánábà 
- Pọ́ọ̀lù 
- Dọ́káàsì 
 
- 11:05 Orin 79 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 Máa Fìfẹ́ Hàn Sáwọn Èèyàn Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù 
- 11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:00 Orin 52 
Ọ̀SÁN
- 1:10 Ohùn Orin 
- 1:20 Orin 107 àti Àdúrà 
- 1:30 Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn: Báwo Ni Ìfẹ́ Tó Jinlẹ̀ Ṣe Ń Gbé Òtítọ́ Lárugẹ? 
- 2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:30 Orin 101 àti Ìfilọ̀ 
- 2:40 Àpínsọ Àsọyé: Mú Kí Ìjọ Máa Dàgbà Sí I - Nífẹ̀ẹ́ Òtítọ́ Bíbélì 
- Mọyì Ọgbọ́n Tó Wà Nínú Òfin Ọlọ́run 
- Máa Gbé Àwọn Ará Ró 
 
- 3:40 “Ẹ Máa Fi Ìfẹ́ Ṣe Gbogbo Ohun Tí Ẹ Bá Ń Ṣe” 
- 4:15 Orin 105 àti Àdúrà