Sunday
“Kí Ọlọ́run tó ń fúnni ní ìrètí fi gbogbo ayọ̀ àti àlàáfíà kún inú yín”—Róòmù 15:13
ÀÁRỌ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 101 àti Àdúrà 
- 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Wọ́n Ṣe Ohun Tó Jẹ́ Kí Àlàáfíà Wà - • Jósẹ́fù Àtàwọn Ẹ̀gbọ́n Rẹ̀ (Gálátíà 6:7, 8; Éfésù 4:32) 
- • Àwọn Ará Gíbíónì (Éfésù 5:17) 
- • Gídíónì (Àwọn Onídàájọ́ 8:2, 3) 
- • Ábígẹ́lì (1 Sámúẹ́lì 25:27-31) 
- • Méfíbóṣétì (2 Sámúẹ́lì 19:25-28) 
- • Pọ́ọ̀lù àti Bánábà (Ìṣe 15:36-39) 
- • Àwọn Àpẹẹrẹ Òde Òní (1 Pétérù 2:17) 
 
- 11:05 Orin 28 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Kí Lo Lè Ṣe Láti Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run? (Jémíìsì 4:8; 1 Jòhánù 4:10) 
- 11:45 Orin 147 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀SÁN
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 23 
- 1:50 FÍDÍÒ: Jèhófà Ń Darí Wa ní Ọ̀nà Àlàáfíà—Apá 2 (Àìsáyà 48:17, 18) 
- 2:30 Orin 139 àti Ìfilọ̀ 
- 2:40 Ó Dájú Pé Àlàáfíà Máa Wà Láyé Àtọ̀run! (Róòmù 16:20; 1 Kọ́ríńtì 15:24-28; 1 Jòhánù 3:8) 
- 3:40 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí