Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kìíní (yp1) Ara Èèpo Iwájú Ìwé Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́! Àlàyé Àjọṣe Rẹ Nínú Ìdílé Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Òbí Mi Sọ̀rọ̀? Kí Nìdí Témi Àtàwọn Òbí Mi Fi Máa Ń Bára Wa Jiyàn? Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Màá Fi Ní Òmìnira Sí I? Kí Nìdí Tí Dádì àti Mọ́mì Fi Fi Ara Wọn Sílẹ̀? Dádì Tàbí Mọ́mì Mi Fẹ́ Ẹlòmíì, Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Un Mọ́ra? Báwo Lọ̀rọ̀ Èmi àti Tẹ̀gbọ́n-Tàbúrò Mi Ṣe Lè Wọ̀ Dáadáa? Àwòkọ́ṣe—Jékọ́bù Ṣé Mo Ti Tó Ẹni Tó Lè Lọ Dá Gbé? Ohun Tí Mo Rò—Àjọṣe Rẹ Nínú Ìdílé Irú Èèyàn Tó O Jẹ́ Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ní Àwọn Ọ̀rẹ́ Tó Dáa? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Borí Ìdẹwò? Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Tọ́jú Ara Mi? Irú Aṣọ Wo Ló Yẹ Kí N Wọ̀? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Túbọ̀ Dá Ara Mi Lójú? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Ìbànújẹ́ Kúrò Lọ́kàn Mi? Àwòkọ́ṣe—Jóòbù Àbí Kí N Para Mi Ni? Ṣé Ó Burú Kéèyàn Tiẹ̀ Láṣìírí Ni? Ṣé Bí Mo Ṣe Ń Kẹ́dùn Dáa Báyìí? Ohun Tí Mo Rò—Irú Èèyàn Tó O Jẹ́ Nílé Ìwé Àtàwọn Ibòmíì Kí Nìdí Táyà Mi Fi Máa Ń Já Láti Sọ Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nílé Ìwé? Ọgbọ́n Wo Ni Mo Lè Dá sí Wàhálà Ilé Ìwé? Ǹjẹ́ Mi Ò Ní Pa Ilé Ìwé Tì Báyìí? Kí Ni Mo Lè Ṣe Kó Má Bàa Sí Wàhálà Láàárín Èmi àti Olùkọ́ Mi? Àwòkọ́ṣe—Mósè Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Fọgbọ́n Lo Àkókò Mi? Èdè àti Àṣà Tàwọn Òbí Mi Yàtọ̀ sí Tibi Tá À Ń Gbé, Kí Ni Kí N Ṣe? Ohun Tí Mo Rò—Nílé Ìwé Àtàwọn Ibòmíì Ọ̀rọ̀ Nípa Ìbálòpọ̀, Ìwà Híhù Àti Ìfẹ́ Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìbẹ́yà-Kannáà-Lòpọ̀? Ṣé Ìbálòpọ̀ Máa Jẹ́ Ká Túbọ̀ Fẹ́ràn Ara Wa? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Fífọwọ́ Pa Ẹ̀yà Ìbímọ Mi? Ṣé Ó Burú Bí Ọkùnrin àti Obìnrin Bá Kàn Gbé Ara Wọn Sùn? Kí Nìdí Táwọn Ọkùnrin Kì Í Fi Í Gba Tèmi? Kí Nìdí Táwọn Obìnrin Kì Í Fi Í Gba Tèmi? Báwo Ni Mo Ṣe Máa Mọ̀ Bóyá Ìfẹ́ Tòótọ́ Ni? Ǹjẹ́ A Ti Ṣe Tán Láti Ṣègbéyàwó Báyìí? Àwòkọ́ṣe—Rúùtù Báwo Ni Màá Ṣe Borí Ẹ̀dùn Ọkàn Mi Bí Àfẹ́sọ́nà Mi Bá Já Mi Sílẹ̀? Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Kó Sọ́wọ́ Àwọn Tó Ń Fipá Báni Lò Pọ̀? Ohun Tí Mo Rò—Ọ̀rọ̀ Nípa Ìbálòpọ̀, Ìwà Híhù Àti Ìfẹ́ Àwọn Ohun Téèyàn Ti Ń Ṣe Ara Rẹ̀ Léṣe Àwọn Ewu Wo Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Sìgá Mímu? Kí Ló Burú Nínú Mímu Ọtí Ní Àmujù? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Lílo Oògùn Olóró? Ohun Tí Mo Rò—Àwọn Ohun Téèyàn Fi Ń Ṣe Ara Rẹ̀ Léṣe Àkókò Tó O Fi Ń Gbádùn Ara Rẹ Ṣé Mi Ò Ti Sọ Ohun Tó Ń Gbé Ìsọfúnni Jáde Di Bárakú? Kí Nìdí Táwọn Òbí Mi Kì Í Fi Í Jẹ́ Kí N Gbádùn Ara Mi? Ohun Tí Mo Rò—Àkókò Tó O Fi Ń Gbádùn Ara Rẹ Ìjọsìn Rẹ Báwo Ni Mo Ṣe Lè Gbádùn Ìjọsìn Ọlọ́run? Báwo Ni Ọwọ́ Mi Ṣe Lè Tẹ Àwọn Ohun Tí Mo Fẹ́ Lé Bá? Àwòkọ́ṣe—Tímótì Ohun Tí Mo Rò—Ìjọsìn Rẹ Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Òbí Ń Béèrè Ibi Tí Mo Kọ Èrò Mi Sí Ara Èèpo Ẹ̀yìn Ìwé Èèpo Ẹ̀yìn Ìwé