- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 9:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 Torí èmi yóò fi gbogbo ìyọnu látọ̀dọ̀ mi kọ lu ọkàn rẹ, àwọn ìránṣẹ́ rẹ àti àwọn èèyàn rẹ, kí o lè mọ̀ pé kò sí ẹlòmíì bí èmi ní gbogbo ayé.+ 
 
-