ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 24:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Màá sọ wọ́n di ohun àríbẹ̀rù àti àjálù lójú gbogbo ìjọba ayé,+ màá jẹ́ kí wọ́n di ẹni ẹ̀gàn àti ẹni àfipòwe, ẹni ẹ̀sín àti ẹni ègún + ní gbogbo ibi tí màá fọ́n wọn ká sí.+

  • Jeremáyà 42:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 “Nítorí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí: ‘Bí mo ṣe da ìbínú mi àti ìrunú mi sórí àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù,+ bẹ́ẹ̀ ni màá da ìrunú mi sórí yín tí ẹ bá lọ sí Íjíbítì, ẹ ó sì di ẹni ègún àti ohun àríbẹ̀rù, ẹni ìfiré àti ẹni ẹ̀gàn,+ ẹ kò sì ní rí ibí yìí mọ́.’

  • Ìdárò 5:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Kí nìdí tí o fi gbàgbé wa pátápátá, tí o sì pa wá tì títí di àkókò yìí?+

  • Dáníẹ́lì 9:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Jèhófà, gẹ́gẹ́ bíi gbogbo ìṣe òdodo rẹ,+ jọ̀ọ́, dáwọ́ ìbínú àti ìrunú rẹ dúró lórí ìlú rẹ, Jerúsálẹ́mù, òkè mímọ́ rẹ; torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa àti àṣìṣe àwọn baba ńlá wa, gbogbo àwọn tó yí wa ká ń gan Jerúsálẹ́mù àti àwọn èèyàn rẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́