Sáàmù 106:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin wọn àti ti àwọn ọmọbìnrin wọnTí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà Kénáánì;+Ilẹ̀ náà sì di ẹlẹ́gbin nítorí ìtàjẹ̀sílẹ̀. Àìsáyà 24:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà ti ba ibẹ̀ jẹ́,+Torí wọ́n ti rú òfin,+Wọ́n ti yí ìlànà pa dà,+Wọ́n sì da májẹ̀mú tó wà pẹ́ títí.*+ Jeremáyà 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Lẹ́yìn náà, mo mú yín wá sí ilẹ̀ eléso,Kí ẹ lè máa jẹ èso rẹ̀ àti àwọn ohun rere rẹ̀.+ Ṣùgbọ́n ẹ wọlé wá, ẹ sì sọ ilẹ̀ mi di ẹlẹ́gbin;Ẹ sọ ogún mi di ohun ìríra.+ Jeremáyà 16:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Lákọ̀ọ́kọ́ ná, màá san ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ohun tó yẹ wọ́n nítorí àṣìṣe wọn àti ẹ̀ṣẹ̀ wọn,+Nítorí wọ́n ti fi àwọn ère aláìlẹ́mìí* ti òrìṣà ẹ̀gbin wọn sọ ilẹ̀ mi di aláìmọ́Wọ́n sì ti fi àwọn ohun ìríra wọn kún inú ogún mi.’”+
38 Wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin wọn àti ti àwọn ọmọbìnrin wọnTí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà Kénáánì;+Ilẹ̀ náà sì di ẹlẹ́gbin nítorí ìtàjẹ̀sílẹ̀.
5 Àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà ti ba ibẹ̀ jẹ́,+Torí wọ́n ti rú òfin,+Wọ́n ti yí ìlànà pa dà,+Wọ́n sì da májẹ̀mú tó wà pẹ́ títí.*+
7 Lẹ́yìn náà, mo mú yín wá sí ilẹ̀ eléso,Kí ẹ lè máa jẹ èso rẹ̀ àti àwọn ohun rere rẹ̀.+ Ṣùgbọ́n ẹ wọlé wá, ẹ sì sọ ilẹ̀ mi di ẹlẹ́gbin;Ẹ sọ ogún mi di ohun ìríra.+
18 Lákọ̀ọ́kọ́ ná, màá san ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ohun tó yẹ wọ́n nítorí àṣìṣe wọn àti ẹ̀ṣẹ̀ wọn,+Nítorí wọ́n ti fi àwọn ère aláìlẹ́mìí* ti òrìṣà ẹ̀gbin wọn sọ ilẹ̀ mi di aláìmọ́Wọ́n sì ti fi àwọn ohun ìríra wọn kún inú ogún mi.’”+