Má Sọ̀rètí Nù Bó O Ṣe Ń Ṣe Ohun Tó Dára!
ÒWÚRỌ̀
- 9:30 [11:30]a Ohùn Orin 
- 9:40 [11:40] Orin 77 àti Àdúrà 
- 9:50 [11:50] Kí Nìdí Tó Fi Ṣòro Láti Ṣe Ohun Tó Dára? 
- 10:05 [12:05] Àpínsọ Àsọyé: Má Ṣe Fúnrúgbìn Pẹ̀lú Níní Ẹran Ara Lọ́kàn - Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò 
- Yan Eré Ìnàjú Tó Bójú Mu 
- Kọjú Ìjà sí Ẹ̀mí Ìlara 
- Máa Lépa Ọjọ́ Ọ̀la Tó Fini Lọ́kàn Balẹ̀ 
 
- 11:05 [1:05] Orin 45 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 [1:15] Máa Ṣe Ohun Rere sí Gbogbo Èèyàn 
- 11:30 [1:30] Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:00 [2:00] Orin 63 
Ọ̀SÁN
- 1:10 [2:40] Ohùn Orin 
- 1:20 [2:50] Orin 127 àti Àdúrà 
- 1:30 [3:00] Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn: Báwo La Ṣe Lè Yẹra fún Fífi Ọlọ́run Ṣe Ẹlẹ́yà? 
- 2:00 [3:30] Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:30 [4:00] Orin 59 àti Ìfilọ̀ 
- 2:40 [4:10] Àpínsọ Àsọyé: Máa Fúnrúgbìn Nípa Ti Ẹ̀mí - Jẹ́ Kó Mọ́ Ẹ Lára Láti Máa Kẹ́kọ̀ọ́ 
- Fi Àwọn Ìlànà Bíbélì Darí Ìgbésí Ayé Rẹ 
- “Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọwọ́ Rẹ Sinmi” 
 
- 3:40 [5:10] Ohun Tá A Máa Ká Tí A Kò Bá Ṣàárẹ̀ 
- 4:15 [5:45] Orin 126 àti Àdúrà 
a Àkókò tó wà nínú àkámọ́ [ ] ni a ó tẹ̀ lé ní Sátidé tó bá jẹ́ ọjọ́ “Gbálùúmọ́”