ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • rsg19
  • Jésù Kristi

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jésù Kristi
  • Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—Ẹ̀dà Ti Ọdún—2019
  • Ìsọ̀rí
  • Ta Ni Jésù?
  • Kó Tó Wá Sáyé
  • Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Jésù Kristi
  • Ìgbésí Ayé Jésù Lórí Ilẹ̀ Ayé
  • Ìwà Jésù
  • Ikú Jésù, Àjíǹde Rẹ̀ àti Ìràpadà
  • Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù
Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—Ẹ̀dà Ti Ọdún—2019
rsg19

Jésù Kristi

Tún wo ìwé:

Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Bíbélì, Àwọn Ẹ̀kọ́

69-93

“Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn”

Olùkọ́

Ọkùnrin Títóbilọ́lá Jù Lọ

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Kí nìdí tá a fi pe Jésù ní Kristi?) Ilé Ìṣọ́, 4/1/2010

“Kristi Agbára Ọlọ́run” Sún Mọ́ Jèhófà, orí 9

Ta Ni Jésù?

Ṣé Jésù Wà Lóòótọ́? Jí!, No. 5 2016

Ta Ni Jésù Kristi? Bíbélì Fi Kọ́ni, orí 4

Òtítọ́ Nípa Baba, Ọmọ, àti Ẹ̀mí Mímọ́ Bíbélì Fi Kọ́ni, Àfikún

❐ Ilé Ìṣọ́, 4/1/2012

Àwọn Èèyàn Ń Wá Ìdáhùn

Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Wa Nípa Jésù Kristi

Ǹjẹ́ Ó Ṣe Pàtàkì Kí Á Mọ Ìdáhùn Tó Tọ̀nà?

Ta Ni Jésù Kristi? Ìròyìn Ayọ̀, ẹ̀kọ́ 4

❐ Ilé Ìṣọ́, 4/1/2011

Ta Ni Jésù Kristi?

Jésù​—⁠Ibo Ló Ti Wá?

Jésù​—⁠Báwo Ló Ṣe Gbé Ìgbé Ayé Rẹ̀?

Jésù​—⁠Kí Nìdí Tó Fi Kú?

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Ǹjẹ́ Jésù tiẹ̀ bá èyíkéyìí lára àwọn àpọ́sítélì rẹ̀ méjìlá tan?) Ilé Ìṣọ́, 9/1/2010

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Báwo ni Jésù àti Jòhánù Oníbatisí ṣe bára wọn tan?) Ilé Ìṣọ́, 9/1/2010

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Ẹ̀rí wo ló wà yàtọ̀ sí ti Bíbélì pé Jésù gbé ayé rí?) Ilé Ìṣọ́, 4/1/2010

Ṣé Irọ́ Ni àbí Òótọ́?​—⁠Ohun Tó Jẹ́ Òótọ́ Nípa Jésù Ilé Ìṣọ́, 4/1/2010

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ṣé Ọmọ Ọlọ́run Ni Jésù Lóòótọ́? Jí!, 4/2006

❐ Ilé Ìṣọ́, 9/15/2005

Ṣé Ọlọ́run Ni Tàbí Èèyàn?

Ta Ni Jésù Kristi?

Jésù Kristi​—⁠Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Ó Wá Sáyé Ilé Ìṣọ́, 6/15/2003

❐ Ilé Ìṣọ́, 12/15/2001

“Ta Ni Àwọn Ènìyàn Ń Sọ Pé Mo Jẹ́?”

Ẹni Náà Gan-an Tí A Ń Pè Ní Jésù

Àwọn Orúkọ Rẹ̀ Mí ì, Àwọn Orúkọ Oyè Rẹ̀ àti Ipa Tó Kó

Ta Ni Máíkẹ́lì Olú-Áńgẹ́lì? Bíbélì Fi Kọ́ni, Àfikún

Mọyì Ipa Tí Kristi Ń Kó Nínú Ìṣètò Ọlọ́run A Ṣètò Wa, orí 2

Ǹjẹ́ O ti Jẹ Búrẹ́dì Tí Ń Fúnni Ní Ìyè? Ilé Ìṣọ́, 6/1/2014

❐ Ilé Ìṣọ́, 2/15/2014

Ẹ Yin Kristi, Ọba Ògo!

Ẹ Yọ̀ Nítorí Ìgbéyàwó Ọ̀dọ́ Àgùntàn!

Kórè Ìbùkún Yanturu Nípasẹ̀ Ọba Tí Ọlọ́run Ń Fi Ẹ̀mí Rẹ̀ Darí! Ilé Ìṣọ́, 12/15/2010

Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé: Ṣé Jésù Ni Máíkẹ́lì Olú Áńgẹ́lì? Ilé Ìṣọ́, 4/1/2010

Bá A Ṣe Lè Rí Ìṣúra Tá A Rọra Fi Pa Mọ́ Sínú Kristi Ilé Ìṣọ́, 7/15/2009

❐ Ilé Ìṣọ́, 4/15/2009

Bá A Ṣe Lè Mọyì Jésù Tó Jẹ́ Mósè Títóbi Jù

Bá A Ṣe Lè Mọyì Jésù Tó Jẹ́ Dáfídì àti Sólómọ́nì Títóbi Jù

Wò Ó! Ìránṣẹ́ Tí Jèhófà Tẹ́wọ́ Gbà Ilé Ìṣọ́, 1/15/2009

Mímọyì Ipa Tó Ṣàrà Ọ̀tọ̀ Tí Jésù Kó Nínú Mímú Ìfẹ́ Ọlọ́run Ṣẹ Ilé Ìṣọ́, 12/15/2008

Jésù Kristi​—⁠Míṣọ́nnárì Tó Ta Yọ Ilé Ìṣọ́, 2/15/2008

“Ọ̀nà àti Òtítọ́ àti Ìyè” “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” orí 2

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ṣé Jésù ni gbólóhùn bí “ẹnì kan ṣoṣo tí ó ní àìkú” àti “ẹni tí kò sí ọ̀kan nínú àwọn ènìyàn tí ó ti rí i tàbí lè rí i” ń tọ́ka sí? Ilé Ìṣọ́, 9/1/2005

Jésù Lè Dáàbò Bò Wá Olùkọ́, orí 33

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ta Ni Máíkẹ́lì Olú-Áńgẹ́lì Náà? Jí!, 2/8/2002

Mèsáyà

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì àtijọ́, ṣé ìgbà gbogbo ni ìlà ìdílé tí Mèsáyà ti wá máa ń gba ọ̀dọ̀ àkọ́bí ọkùnrin kọjá? Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 12/2017

Jésù Kristi Ni Mèsáyà Tí Ọlọ́run Ṣèlérí Bíbélì Fi Kọ́ni, Àfikún

Kí Nìdí Tí Wọ́n Fi Kọ Mèsáyà Sílẹ̀? Ilé Ìṣọ́, 12/1/2010

Mèsáyà Dé Ìgbàgbọ́ Òdodo, apá 8

Mèsáyà! Ọ̀nà Ìgbàlà Tí Ọlọ́run Pèsè Ilé Ìṣọ́, 12/15/2009

Mèsáyà Dé Kí Ló Wà Nínú Bíbélì, apá 16

Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Nípa Mèsáyà Ilé Ìṣọ́, 10/1/2008

❐ Ilé Ìṣọ́, 2/15/2006

Àǹfààní Wo Ni Mèsáyà Máa Ṣe fún Wa?

“Àwa Ti Rí Mèsáyà Náà”

Kó Tó Wá Sáyé

Ẹ̀yin Ọkùnrin, Ṣé Ẹ̀ Ń Tẹrí Ba fún Ipò Orí Kristi? Ilé Ìṣọ́, 5/15/2010 ¶10

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Báwo la ṣe mọ̀ pé Jésù Kristi ni ọgbọ́n tá a ṣàpèjúwe nínú Òwe 8:22-31? Ilé Ìṣọ́, 8/1/2006

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Lọ́nà wo la gbà dá ohun gbogbo “fún” Jésù? (Kól. 1:16) Ilé Ìṣọ́, 9/1/2001

Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Jésù Kristi

Ojú Ìwòye Bíbélì: Mèsáyà Jí!, 3/2015

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Kí ló mú kí àwọn Júù ọ̀rúndún kìíní máa “fojú sọ́nà” fún Mèsáyà? Ilé Ìṣọ́, 2/15/2014

Ìbéèrè 6: Kí ni Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ nípa Mèsáyà? Ohun Tó Wà Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Mélòó ni àsọtẹ́lẹ̀ nípa Mèsáyà tó wà nínú Bíbélì? Ilé Ìṣọ́, 8/15/2011

Wọ́n Rí Mèsáyà! Ilé Ìṣọ́, 8/15/2011

❐ Ilé Ìṣọ́, 1/15/2009

Wò Ó! Ìránṣẹ́ Tí Jèhófà Tẹ́wọ́ Gbà

Ìránṣẹ́ Jèhófà Tí Wọ́n ‘Gún Nítorí Ìrélànàkọjá Wa’

“Òfin Ti Di Akọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Wa” Ilé Ìṣọ́, 3/1/2008

❐ Ilé Ìṣọ́, 2/15/2006

Àǹfààní Wo Ni Mèsáyà Máa Ṣe fún Wa?

“Àwa Ti Rí Mèsáyà Náà”

Kristi Làwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Tọ́ka Sí Ilé Ìṣọ́, 1/15/2005

❐ Ilé Ìṣọ́, 9/15/2000

“Wákàtí Rẹ̀ Kò Tí ì Dé”

“Wákàtí Náà Ti Dé!”

Máa Fiyè Sí Ọ̀rọ̀ Àsọtẹ́lẹ̀ Ọlọ́run Ilé Ìṣọ́, 4/1/2000

Ìgbésí Ayé Jésù Lórí Ilẹ̀ Ayé

Báwo Ni Jésù Ṣe Rí Gan-an? Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde), No. 6 2017

Jésù Máa Ń Ṣègbọràn Ní Gbogbo Ìgbà Kọ́ Ọmọ Rẹ, ẹ̀kọ́ 10

4-A Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù​—⁠Ohun Tó Ṣẹlẹ̀ Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Jésù Tó Bẹ̀rẹ̀ Àfikún Ìsọfúnni

Kọ́ Ọmọ Rẹ: Jésù Kẹ́kọ̀ọ́ Láti Jẹ́ Onígbọràn Ilé Ìṣọ́, 4/1/2010

Ẹ̀kọ́ Tí A Lè Rí Kọ́ Lára Mèsáyà Tó Jẹ́ Aṣáájú Ìgbàgbọ́ Òdodo, apá 9

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Èdè wo ni Jésù sọ nígbà tó wà láyé?) Ilé Ìṣọ́, 8/1/2008

❐ Ilé Ìṣọ́, 12/15/2003

Àwọn Wo Ló Wà Nínú Ìdílé Tá A Ti Bí Jésù?

Ẹ̀kọ́ Tá A Lè Rí Kọ́ Lára Òbí Àtàwọn Àbúrò Jésù

Ìbí Jésù

Àwọn Áńgẹ́lì Kéde Pé Wọ́n Bí Jésù Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Bíbélì, ẹ̀kọ́ 70

Jèhófà Dáàbò Bo Jésù Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Bíbélì, ẹ̀kọ́ 71

Ṣé Oṣù December Ni Wọ́n Bí Jésù? Bíbélì Fi Kọ́ni, Àfikún

Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé: Ṣé Lóòótọ́ Ni Àwọn Amòye Mẹ́ta Lọ Wo Jésù Nígbà Tó Wà Ní Ọmọ Ọwọ́? Ilé Ìṣọ́, 12/1/2009

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ìgbà Wo Ni Wọ́n Bí Jésù? Jí!, 1/2009

Ọ̀nà Tí Ìbí Jésù Gbà Mú Àlàáfíà Wá Ilé Ìṣọ́, 12/15/2006

❐ Ilé Ìṣọ́, 12/15/2004

Ìṣẹ̀lẹ̀ Mánigbàgbé Kan

Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Rántí Jésù Kristi?

“Èyí Ni Ọmọ Mi” Olùkọ́, orí 5

❐ Ilé Ìṣọ́, 12/15/2002

Ọ̀nà Tí A Gbà Bí Jésù àti Ìdí Tí A Fi Bí I

Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó Wà Nínú Àkọsílẹ̀ Ìbí Jésù

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ǹjẹ́ àìpé Màríà wúńdíá ran oyún Jésù? Ilé Ìṣọ́, 3/15/2002

Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Jésù, Iṣẹ́ Ìyanu Rẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ Rẹ̀

Tún wo ìwé:

Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Bíbélì, Àwọn Ẹ̀kọ́ 74-93

Ọkùnrin Títóbilọ́lá Jù Lọ

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Kí ló ṣàrà ọ̀tọ̀ nínú bí Jésù ṣe hùwà sáwọn adẹ́tẹ̀?) Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde), No. 4 2016

❐ Ilé Ìṣọ́, 6/15/2015

Kristi​—⁠Agbára Ọlọ́run

Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Èèyàn

Ìjọba Ọlọ́run​—⁠Kí Nìdí Tó fi Ṣe Pàtàkì Gan-an sí Jésù Ilé Ìṣọ́, 10/1/2014

“Kí Ìjọba Rẹ Dé” Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso orí 1

❐ Àfikún Ìsọfúnni

4-B Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù​—⁠Ìgbà Tí Jésù Bẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ̀

4-C Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù​—⁠Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Títayọ Tí Jésù Ṣe ní Gálílì (Apá 1)

4-D Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù​—⁠Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Títayọ Tí Jésù Ṣe ní Gálílì (Apá 2)

4-E Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù​—⁠Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Títayọ tí Jésù Ṣe ní Gálílì (Apá 3) àti ní Jùdíà

4-F Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù​—⁠Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Pa Dà Lọ Ṣe ní Ìlà Oòrùn Jọ́dánì

4-G Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù​—⁠Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Ṣe Kẹ́yìn ní Jerúsálẹ́mù (Apá 1)

4-H Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù​—⁠Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Ṣe Kẹ́yìn ní Jerúsálẹ́mù (Apá 2)

‘Ọmọ Fẹ́ Láti Ṣí Baba Payá’ Ilé Ìṣọ́, 4/15/2012

❐ Ilé Ìṣọ́, 4/1/2010

Ọkùnrin Tó Ṣe Ohun Tó Ta Yọ Jù Lọ Fáráyé

Ipa Rere Tí Ẹ̀kọ́ Jésù Kristi Ní Lórí Àwọn Èèyàn

Ohun Tí Jésù Kọ́ni Nípa Ara Rẹ̀

Ohun Tí Jésù Kọ́ni Nípa Ọlọ́run

Ohun Tí Jésù Kọ́ni Nípa Ìjọba Ọlọ́run

Bí Iṣẹ́ Tí Jésù Kristi Jẹ́ Ṣe Kàn Ẹ́

Bí Ọ̀rọ̀ Jésù Ṣe Lè Sọni Di Aláyọ̀ Ilé Ìṣọ́, 2/15/2009

Jésù Kọ́ni Nípa Ìjọba Ọlọ́run Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?, apá 17

Jésù Ṣe Iṣẹ́ Ìyanu Kí Ló Wà Nínú Bíbélì, apá 18

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Kí nìdí tó fi jẹ́ pé díẹ̀díẹ̀ ni Jésù ń la ojú afọ́jú kan?) Ilé Ìṣọ́, 4/1/2008

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Kí nìdí tó fi gba Jésù ní ọjọ́ mẹ́rin gbáko kó tó lè dé ibi ibojì Lásárù?) Ilé Ìṣọ́, 1/1/2008

“Ènìyàn Mìíràn Kò Tíì Sọ̀rọ̀ Báyìí Rí” “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” orí 11

❐ Ilé Ìṣọ́, 7/15/2004

Àwọn Iṣẹ́ Ìyanu Jésù Ṣóòótọ́ Ni àbí Ìtàn Àròsọ?

Àwọn Iṣẹ́ Ìyanu Jésù Kí Lo Lè Rí Kọ́ Látinú Wọn?

Ìbéèrè Látọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Ṣé ràkúnmí gidi àti abẹ́rẹ́ ìránṣọ ni Jésù ní lọ́kàn? Ilé Ìṣọ́, 5/15/2004

Ohun Tó Mú Kí Jésù Jẹ́ Olùkọ́ Ńlá Olùkọ́, orí 1

❐ Ilé Ìṣọ́, 9/1/2002

“Ènìyàn Mìíràn Kò Tí ì Sọ̀rọ̀ Báyìí Rí”

“Kì Í Bá Wọn Sọ̀rọ̀ Láìsí Àpèjúwe”

Máa Fara Wé Olùkọ́ Ńlá Náà

Àpèjúwe

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Ṣé èébú ni àpèjúwe tí Jésù ṣe nípa “ajá kéékèèké” jẹ́?) Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde), No. 5 2017

❐ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2015

Èyí Ni “Ọ̀nà Tí Ìwọ Tẹ́wọ́ Gbà”

Ṣé Wàá “Máa Bá A Nìṣó Ní Ṣíṣọ́nà”?

Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àpèjúwe Nípa Àwọn Tálẹ́ńtì Náà

Máa Fi Ìdúróṣinṣin Ti Àwọn Arákùnrin Kristi Lẹ́yìn

❐ Ilé Ìṣọ́, 12/15/2014

‘Ẹ Fetí sí Mi, Kí Ẹ sì Lóye Ìtúmọ̀ Rẹ̀’

Ǹjẹ́ O “Mòye Ìtúmọ̀ Ìwé Mímọ́”?

“Kì Í Bá Wọn Sọ̀rọ̀ Láìsí Àpèjúwe” “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” orí 12

Ìwà Jésù

Tún wo ìwé:

“Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” orí 3 sí 6,

15 àti 16

❐ Ilé Ìṣọ́, 2/15/2015

Ẹ Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ àti Oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ Bíi Ti Jésù

Ẹ Jẹ́ Onígboyà Kẹ́ Ẹ sì Máa Lo Ìfòyemọ̀ Bíi Ti Jésù

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Kí ló fà á tí Jésù fi da omijé lójú kó tó jí Lásárù dìde? (Jòhánù 11:35) Ilé Ìṣọ́, 9/15/2013

Jésù Kọ́ Wa Láti Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 11/15/2012

Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Sùúrù Jèhófà àti Jésù Ilé Ìṣọ́, 9/15/2012

Ohun Tá A Fi Ń Rántí Àwọn Kan (§ Kí Làwọn Èèyàn Fi Ń Rántí Jésù?; § Jésù Yọ́nú Sáwọn Obìnrin) Ilé Ìṣọ́, 8/15/2003

“Mo Fi Àwòṣe Lélẹ̀ fún Yín” Ilé Ìṣọ́, 8/15/2002

Jésù Fi “Ọgbọ́n Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run” Hàn Sún Mọ́ Jèhófà, orí 21

“Láti Mọ Ìfẹ́ Kristi” Sún Mọ́ Jèhófà, orí 29

Ikú Jésù, Àjíǹde Rẹ̀ àti Ìràpadà

Tún wo Ìrántí Ikú Kristi lábẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lábẹ́ Ìjọ Kristẹni

Wọ́n Pa Jésù ní Gọ́gọ́tà Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Bíbélì, ẹ̀kọ́ 90

Jésù Jíǹde Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Bíbélì, ẹ̀kọ́ 91

Jósẹ́fù ará Arimatíà Lo Ìgboyà Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 10/2017

❐ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́), 2/2017

Ohun Tí Jèhófà Ní Lọ́kàn Máa Ṣẹ!

Ìràpadà “Ọrẹ Pípé” Tí Baba Fún Wa

❐ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde), No. 2 2017

Ẹ̀bùn Tó Ju Gbogbo Ẹ̀bùn Lọ

Kí Nìdí Tí Ẹ̀bùn Yìí Fi Ṣe Iyebíye Gan-an?

Kí Lo Máa Ṣe sí Ẹ̀bùn Ọlọ́run Tó Dára Jù Lọ?

❐ Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde), No. 2 2016

Ṣé Lóòótọ́ Ló Ṣẹlẹ̀?

Kí Nìdí Tí Jésù Fi Jìyà Tó sì Kú?

❐ Ilé Ìṣọ́, 3/1/2015

Ìdí Tí A Fi Nílò Ìgbàlà

Ikú àti Àjíǹde Jésù​—⁠Àǹfààní Tó Ṣe fún Ẹ́

Ìràpadà​—⁠Ẹ̀bùn Tó Ṣeyebíye Jù Lọ Tí Ọlọ́run Fúnni Bíbélì Fi Kọ́ni, orí 5

Àjíǹde Jésù​—⁠Àǹfààní Wo ló Ṣe Wá Ilé Ìṣọ́, 11/15/2014

Gẹ́gẹ́ Bí Ọ̀tá Ìkẹyìn, Ikú Di Ohun Asán Ilé Ìṣọ́, 9/15/2014

Ohun Tí Ọlọ́run Ti Ṣe Fún Ẹ Ilé Ìṣọ́, 3/1/2014

Ṣé Òótọ́ Ni Pé Jésù Jíǹde? Ilé Ìṣọ́, 3/1/2013

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Ṣé bí àwọn Júù ṣe máa ń sìnkú ni wọ́n ṣe sin Jésù?) Ilé Ìṣọ́, 3/1/2013

❐ Àfikún Ìsọfúnni

16-A Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá 1)

16-B Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá 2)

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Kí nìdí tí ọ̀nà tí Jésù gbà kú fi fa ìkọ̀sẹ̀ fún àwọn kan lára àwọn Júù?) Ilé Ìṣọ́, 5/1/2012

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Kí ni ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ọ̀daràn tí wọ́n kàn mọ́gi lẹ́gbẹ̀ẹ́ Jésù?) Ilé Ìṣọ́, 2/1/2012

Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé: Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Sọ Pé Kí Ábúráhámù Fi Ọmọ Rẹ̀ Rúbọ? Ilé Ìṣọ́, 1/1/2012

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Wákàtí wo gan-an ni wọ́n kan Jésù mọ́gi? Ilé Ìṣọ́, 11/15/2011

Ọlọ́run Dámọ̀ràn Ìfẹ́ Rẹ̀ fún Wa Ilé Ìṣọ́, 6/15/2011

Ìgbẹ́jọ́ Tó Burú Jù Lọ Láyé Ilé Ìṣọ́, 4/1/2011

Ṣé Ò Ń Múra Sílẹ̀ Fún Ọjọ́ Tó Ṣe Pàtàkì Jù Lọ Nínú Ọdún? (Àtẹ Ìsọfúnni: Ọ̀sẹ̀ Tó Kẹ́yìn) Ilé Ìṣọ́, 2/1/2011

Ǹjẹ́ O Mọyì Ohun Tí Jèhófà Ṣe Láti Dá Ọ Nídè? Ilé Ìṣọ́, 9/15/2009

Ǹjẹ́ O Mọ̀? (§ Kí nìdí tí ẹ̀wù àwọ̀tẹ́lẹ̀ Jésù wu àwọn ọmọ ogun Róòmù?) Ilé Ìṣọ́, 7/1/2009

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Báwo làwọn Júù ṣe “gbé ìgbésẹ̀ ní àìmọ̀” nígbà tí wọ́n ní kí wọ́n pa Jésù? (Ìṣe 3:17) Ilé Ìṣọ́, 6/15/2009

Wọ́n Pa Jésù Kristi Kí Ló Wà Nínú Bíbélì, apá 20

Jésù Jíǹde! Kí Ló Wà Nínú Bíbélì, apá 21

Bí Ikú Jésù Ṣe Lè Gbà Ọ́ Ilé Ìṣọ́, 3/1/2008

Ìràpadà Túbọ̀ Fi Òdodo Ọlọ́run Hàn Ilé Ìṣọ́, 11/1/2005

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Kí nìdí tí Jésù fi ní kí Tọ́másì fọwọ́ kan òun àmọ́ tí kò gba Màríà Magidalénì láyè? Ilé Ìṣọ́, 12/1/2004

Fi Ojú Pàtàkì Wo Ẹ̀bùn Ìwàláàyè Rẹ Ilé Ìṣọ́, 6/15/2004

Ọlọ́run Rántí Ọmọ Rẹ̀ Olùkọ́, orí 39

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé: Kí ni ọ̀rọ̀ náà “nígbàkúùgbà tí ẹ bá ń jẹ ìṣù búrẹ́dì yìí, tí ẹ sì ń mu ife yìí” túmọ̀ sí? Ilé Ìṣọ́, 1/1/2003

Jèhófà Pèsè “Ìràpadà ní Pàṣípààrọ̀ fún Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ènìyàn” Sún Mọ́ Jèhófà, orí 14

❐ Ilé Ìṣọ́, 11/15/2001

Ǹjẹ́ Ìrètí Kankan Tiẹ̀ Wà Pé A Ó Gbà Wá Là?

Jésù Ń Gbani Là​—⁠Lọ́nà Wo?

❐ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2001

Àjíǹde Jésù Wà Lábẹ́ Àyẹ̀wò Fínnífínní

“Ní Ti Tòótọ́ Ni A Gbé Olúwa Dìde!”

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù

Ẹ Wà Lójúfò Bíi Ti Jésù Ilé Ìṣọ́, 2/15/2012

Ṣé Ò Ń Tọ Kristi Lẹ́yìn Nígbà Gbogbo? Ilé Ìṣọ́, 4/15/2010

“Ọ̀rẹ́ Mi Ni Yín” Ilé Ìṣọ́, 10/15/2009

Ẹ Máa Hùwà Bíi Kristi Ilé Ìṣọ́, 9/15/2009

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Tẹ̀ Lé “Kristi”? Ilé Ìṣọ́, 5/15/2009

❐ Ilé Ìṣọ́, 12/1/2008

Ohun Táwọn Èèyàn Sọ Nípa Jésù

Àpẹẹrẹ Àtàtà Tó Yẹ Ká Fara Wé Ni Jésù

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù​—⁠Sin Ọlọ́run bí Ọlọ́run Ṣe Fẹ́ Ilé Ìṣọ́, 9/15/2008

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Míṣọ́nnárì Tó Ta Yọ Ilé Ìṣọ́, 2/15/2008

“Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn”​—⁠Kí Ni Jésù Ní Lọ́kàn? “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” orí 1

“Máa Bá A Lọ ní Títọ̀ Mí Lẹ́yìn” “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” orí 18

Máa Bá A Lọ ní Títẹ̀lé Ìṣísẹ̀ Jésù Kristi Ilé Ìṣọ́, 9/15/2005

❐ Ilé Ìṣọ́, 3/15/2005

Kárí Ayé Làwọn Èèyàn Mọyì Jésù

Ipa Wo Ni Jésù Kristi Ń Ní Lórí Rẹ?

Ẹ Máa Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Tí Jésù Fi Lélẹ̀ Ilé Ìṣọ́, 1/1/2005

Bí A Ṣe Lè Ní Èrò Kristi Nípa Ipò Ọlá Ilé Ìṣọ́, 8/1/2004

“Ẹ Mọ́kànle! Mo Ti Ṣẹ́gun Ayé” Ilé Ìṣọ́, 3/15/2003

Àwọn Tó Di Ọmọ Ẹ̀yìn Jésù Olùkọ́, orí 13

Ìdí Tó Fi Yẹ Kí Á Fẹ́ràn Jésù Olùkọ́, orí 38

Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? Bí A Ṣe Lè Fi Hàn Pé À Ń Fẹ́ Ẹ Olùkọ́, orí 45

“Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn Nígbà Gbogbo” Ilé Ìṣọ́, 8/15/2002

Ṣé Lóòótọ́ Lo Gbà Pé Kristi Ni Aṣáájú Wa? Ilé Ìṣọ́, 3/15/2002

‘Ẹ Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Mi’ Ilé Ìṣọ́, 12/15/2001

Ẹ Ní Ẹ̀mí Ìrònú Kristi Ilé Ìṣọ́, 9/1/2000

Ojú Ìwòye Bíbélì: Ǹjẹ́ Ó Tọ̀nà Láti Máa Jọ́sìn Jésù? Jí!, 4/8/2000

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́