14 Àwọn àgbààgbà Júù ń bá iṣẹ́ ìkọ́lé náà lọ, wọ́n ń tẹ̀ síwájú,+ àsọtẹ́lẹ̀ wòlíì Hágáì+ àti Sekaráyà+ ọmọ ọmọ Ídò sì ń fún wọn níṣìírí; wọ́n parí iṣẹ́ ìkọ́lé náà nípa àṣẹ Ọlọ́run Ísírẹ́lì+ àti nípa àṣẹ Kírúsì+ àti Dáríúsì+ àti Atasásítà+ ọba Páṣíà.
2Ní oṣù Nísàn,* ní ogún ọdún + Ọba Atasásítà,+ wáìnì wà níwájú ọba, mo gbé wáìnì bí mo ti máa ń ṣe, mo sì gbé e fún ọba.+ Àmọ́ mi ò fajú ro níwájú rẹ̀ rí.