-
2 Sámúẹ́lì 18:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Nígbà náà, àwọn ìránṣẹ́ mẹ́wàá tó ń gbé àwọn ohun ìjà Jóábù wá, wọ́n sì kọ lu Ábúsálómù títí ó fi kú.+
-
-
2 Sámúẹ́lì 20:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ní kíá, ọlọ́gbọ́n obìnrin náà wọlé lọ bá gbogbo àwọn èèyàn náà, wọ́n gé orí Ṣébà ọmọ Bíkíráì, wọ́n sì jù ú sí Jóábù. Ni ó bá fun ìwo, wọ́n tú ká kúrò ní ìlú náà, kálukú sì lọ sí ilé rẹ̀;+ Jóábù wá pa dà sí Jerúsálẹ́mù lọ́dọ̀ ọba.
-