7Láyé ìgbà Áhásì+ ọmọ Jótámù ọmọ Ùsáyà, ọba Júdà, Résínì ọba Síríà àti Pékà+ ọmọ Remaláyà, ọba Ísírẹ́lì wá gbógun ja Jerúsálẹ́mù, àmọ́ kò* ṣẹ́gun rẹ̀.+
1Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ fún Míkà*+ ará Móréṣétì, nínú ìran tó rí nípa Samáríà àti Jerúsálẹ́mù láyé ìgbà Jótámù,+ Áhásì+ àti Hẹsikáyà,+ tí wọ́n jẹ́ ọba Júdà:+