- 
	                        
            
            Àìsáyà 13:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Ará Arébíà kankan ò ní pàgọ́ síbẹ̀, Olùṣọ́ àgùntàn kankan ò sì ní jẹ́ kí agbo ẹran rẹ̀ sinmi níbẹ̀. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 50:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Nítorí orílẹ̀-èdè kan ti wá gbéjà kò ó láti àríwá.+ Ó ti sọ ilẹ̀ rẹ̀ di ohun àríbẹ̀rù; Kò sì sí ẹni tó ń gbé inú rẹ̀. Èèyàn àti ẹranko ti fẹsẹ̀ fẹ; Wọ́n ti lọ.” 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 51:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        29 Ilẹ̀ ayé á mì tìtì, jìnnìjìnnì á sì bá a, Nítorí pé èrò Jèhófà sí Bábílónì máa ṣẹ Láti sọ ilẹ̀ Bábílónì di ohun àríbẹ̀rù, tí ẹnì kánkán kò ní gbé ibẹ̀.+ 
 
-